Molẹbi akẹkọọ fasiti OAU, Timothy Adegoke, to padanu ẹmi si ile itura kan niluu Ile Ife ti ni ọkan lara awọn olujẹjọ to n jẹjọ lori iku oloogbe, Oloye Ramon Adedoyin ko figba ...
Wo awọn nnkan to yẹ ki o mọ nipa Alaafin Ọyọ tuntun, Ọba Akeem Abimbola Owoade Lẹyin ọdun mẹta ti awuyewuye ti rọ mọ ipo Alaafin Ọyọ ati ori itẹ Alaafin ana, Ọba ...