Molẹbi akẹkọọ fasiti OAU, Timothy Adegoke, to padanu ẹmi si ile itura kan niluu Ile Ife ti ni ọkan lara awọn olujẹjọ to n jẹjọ lori iku oloogbe, Oloye Ramon Adedoyin ko figba ...
Ileeṣẹ ologun ilẹ wa ti fidi ẹ mulẹ, pe ṣọja mẹfa lo jade laye ninu ikọlu awọn ẹgbẹ alakatakiti ti a mọ si 'Islamic State in West Africa' (ISWAP), to waye ni Sabon Gari ...